nigLyrics - Nigerian Music Lyrics Online Collection
  • Artiste
  • Title
  • Album
  • Genre
  • Year
 A  B  C  D  E  F  G  H  I  J  K  L  M  N  O  P  Q  R  S  T  U  V  W  X  Y  Z  0-9 
 A  B  C  D  E  F  G  H  I  J  K  L  M  N  O  P  Q  R  S  T  U  V  W  X  Y  Z  0-9 
 A  B  C  D  E  F  G  H  I  J  K  L  M  N  O  P  Q  R  S  T  U  V  W  X  Y  Z  0-9 
 RnB  HipHop  Gbedu  Reggae  Soul  Rock  DanceHall  Naija  HighLife  AfroBeat  Gospel 
 1900-1960  1961-1990  1991-2000  2001  2002  2003  2004  2005  2006  2007  2008 

Ijoba Orun lyrics

Artiste(s): Lara George
Title: Ijoba Orun
Album: Single
Genre: Gospel
Year Realeased: 2008
Uhhhuhhhh
Uhuh

Ijoba orun
Ere Onigbagbo o
Ijoba orun
Ere Onigbagbo o

Ma je n kuna
Baba
Mu mi dele o
Ma je n kuna
Baba se
Mu mi dele o

Owo ti mo ni
ko le mu mi dele o
Moto ti mo ri ra
ko le wa mi dele o
Ore ti mo ni
ko le sinmi dele o
Gbogbo iwe ti mo ri ka
won o le gbe mi dele o

[lyrics from www.niglyrics.com]

Ma je n kuna
Baba
Mu mi dele o
ki n ma ku sajo bi efin
Mu mi dele o
Aye loja, oorun ni ile
Mu mi dele o
Aye loja yi, oorun nile se
Mu mi dele o

Mu mi dele o (x8)
Ma ma je n kuna
Baba ooo
Baba ooo
Mu mi dele o (x5)

Ile ogo
Ile ayo, Ile ayo
Ile alafia
Ile ogo
Ile ayo, Ile ayo
Ile alafia

Ijoba orun
Ere onigbagbo o
Ijoba oorun
Ere onigbagbo o
Ma je n kuna
Impress your friends: Share on Facebook || Send to messenger contacts
Related Lyrics: Cinwe Ike - - Lee Lee - -